Where Egba people?, oya shareORIKI EGBAEgba mo’lisaOmo gbongbo akalaOmo erin jogun olaOmo osi’lekun pa’lekun deAridi ogo loju Ogun Baba t’emi la royin ogun baara fagbeKo sohun ti won n se ni meccaT’awa kii se Legba AlakeWon n mumi semi semi ni MeccaAwa n mumi Odo Ogun legba AlakeWon n g’Arafa ni Mecca Awa n gori Olumo l’egba tiwaWon bimi L’akeMo gbo lenu bi jejeWon bimi ni Gbag...